Nọmba 26:13-15 BIBELI MIMỌ (BM) ìdílé Sera ati ti Ṣaulu. Gbogbo àwọn tí a kà ninu ẹ̀yà Simeoni jẹ́ ẹgbaa mọkanla ó lé igba (22,200).