Nọmba 25:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose sì wí fún àwọn onídàájọ́ Israẹli pé, “Olukuluku yín gbọdọ̀ pa àwọn eniyan rẹ̀ tí ó lọ sin oriṣa Baali tí ó wà ní Peori.”

Nọmba 25

Nọmba 25:1-13