Nọmba 25:16-18 BIBELI MIMỌ (BM)

16. OLUWA sọ fún Mose pé,

17. “Kọlu àwọn ará Midiani, kí o sì pa wọ́n run

18. nítorí ibi tí wọ́n ṣe, ati títàn tí wọ́n tàn yín ní Peori, ati nítorí ọ̀rọ̀ Kosibi, ọmọ baálé kan ní ilẹ̀ Midiani, arabinrin wọn, tí a pa nígbà àjàkálẹ̀ àrùn ti Peori.”

Nọmba 25