Nọmba 25:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli pàgọ́ sí àfonífojì Ṣitimu, àwọn ọkunrin wọn ń bá àwọn ọmọbinrin Moabu tí wọ́n wà níbẹ̀ ṣe àgbèrè.

Nọmba 25

Nọmba 25:1-5