Nọmba 24:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dùbúlẹ̀, ó ba bíi kinniun,bí abo kinniun tí ó sùn, ta ló lè jí i dìde?Ibukun ni fún ẹni tí ó bá súre fún Israẹli,ẹni tí ó bá sì gbé Israẹli ṣépè, olúwarẹ̀ gbé!”

Nọmba 24

Nọmba 24:8-17