Nọmba 24:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wo ọjọ́ iwájú rẹ,mo sì rí ẹ̀yìn ọ̀la rẹ.Ìràwọ̀ kan yóo jáde wá láàrin àwọn ọmọ Jakọbu,ọ̀pá àṣẹ yóo ti ààrin àwọn ọmọ Israẹli jáde wá;yóo run àwọn àgbààgbà Moabu,yóo sì wó àwọn ará Seti palẹ̀.

Nọmba 24

Nọmba 24:9-23