Nọmba 24:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí fi òwe sọ̀rọ̀, pé,“Ọ̀rọ̀ Balaamu ọmọ Beori nìyí,ọ̀rọ̀ ẹni tí ó ríran dájúdájú.

Nọmba 24

Nọmba 24:14-25