Nọmba 24:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Balaamu rí i pé OLUWA ń súre fún àwọn ọmọ Israẹli, kò lọ bíi ti iṣaaju láti bá OLUWA pàdé. Ṣugbọn ó kọjú sí aṣálẹ̀,

Nọmba 24

Nọmba 24:1-6