Nọmba 23:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Balaamu sọ fún Balaki pé, “Kọ́ pẹpẹ ìrúbọ meje kí o sì mú akọ mààlúù meje ati àgbò meje wá.”

Nọmba 23

Nọmba 23:20-30