Nọmba 23:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Balaki sọ fún Balaamu pé, “N óo mú ọ lọ sí ibòmíràn bóyá Ọlọrun yóo gbà pé kí o bá mi ṣépè lé àwọn eniyan náà níbẹ̀.”

Nọmba 23

Nọmba 23:26-30