Nọmba 23:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Wo orílẹ̀-èdè Israẹli! Ó dìde dúró bí abo kinniun,ó sì gbé ara rẹ̀ sókè bíi kinniun.Kò ní sinmi títí yóo fi jẹ ẹran tí ó pa tán,tí yóo sì fi mu ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ tán.”

Nọmba 23

Nọmba 23:22-28