Nọmba 23:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò rí ìparun ninu Jakọbu,bẹ́ẹ̀ ni kò rí ìpọ́njú níwájú Israẹli.OLUWA Ọlọrun wọn wà pẹlu wọn,Òun sì ni ọba wọn.

Nọmba 23

Nọmba 23:18-27