Nọmba 22:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Níbẹ̀ ni Balaki ti fi akọ mààlúù ati aguntan ṣe ìrúbọ, ó sì fún Balaamu ati àwọn àgbààgbà tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ ninu ẹran náà.

Nọmba 22

Nọmba 22:37-41