Nọmba 22:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni OLUWA la Balaamu lójú láti rí angẹli tí ó dúró lójú ọ̀nà pẹlu idà lọ́wọ́ rẹ̀, Balaamu sì dojúbolẹ̀.

Nọmba 22

Nọmba 22:30-35