Nọmba 22:17 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo sọ ọ́ di eniyan pataki, ohunkohun tí o bá sọ, n óo ṣe é. Jọ̀wọ́ wá bá mi ṣépè lé àwọn eniyan wọnyi.”

Nọmba 22

Nọmba 22:14-24