Nọmba 22:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Balaki tún rán àwọn àgbààgbà mìíràn tí wọ́n pọ̀, tí wọ́n sì ṣe pataki ju àwọn ti iṣaaju lọ sí ọ̀dọ̀ Balaamu.

Nọmba 22

Nọmba 22:13-23