Nọmba 21:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose rán eniyan lọ ṣe amí Jaseri, wọ́n sì gba àwọn ìlú agbègbè rẹ̀, wọ́n lé àwọn ará Amori tí ń gbé inú rẹ̀ kúrò.

Nọmba 21

Nọmba 21:24-35