Nọmba 21:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Kànga tí àwọn ọmọ aládé gbẹ́,tí àwọn olórí wàpẹlu ọ̀pá àṣẹ ọba ati ọ̀pá ìtẹ̀lẹ̀ wọn.”Wọ́n sì ṣí kúrò níbẹ̀ lọ sí aṣálẹ̀ Matana.

Nọmba 21

Nọmba 21:17-23