Nọmba 21:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti ibẹ̀, wọ́n ṣí lọ sí Beeri, níbi kànga tí ó wà níbẹ̀ ni OLUWA ti sọ fún Mose pé, “Pe àwọn eniyan náà jọ, n óo sì fún wọn ní omi.”

Nọmba 21

Nọmba 21:12-20