Nọmba 21:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí wọ́n kúrò ní Obotu wọ́n pa àgọ́ sí Òkè-Abarimu ní aṣálẹ̀ tí ó wà níwájú Moabu, ní ìhà ìlà oòrùn.

Nọmba 21

Nọmba 21:2-13