Nọmba 20:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose ati Aaroni kúrò níwájú àwọn eniyan náà, wọ́n lọ dúró ní ẹnu ọ̀nà Àgọ́ Àjọ, wọ́n dojúbolẹ̀, ògo OLUWA sì farahàn.

Nọmba 20

Nọmba 20:1-15