Nọmba 20:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn eniyan náà mọ̀ pé Aaroni ti kú, wọ́n ṣọ̀fọ̀ rẹ̀ fún ọgbọ̀n ọjọ́.

Nọmba 20

Nọmba 20:26-29