Nọmba 19:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó sun mààlúù náà gbọdọ̀ wẹ̀ kí ó sì fọ aṣọ rẹ̀, òun náà yóo jẹ́ aláìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ náà.

Nọmba 19

Nọmba 19:1-16