Nọmba 19:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnikẹ́ni tí ó bá fọwọ́ kan ẹni tí wọ́n fi idà pa, tabi òkú, tabi egungun òkú tabi ibojì òkú ninu pápá yóo di aláìmọ́ fún ọjọ́ meje.

Nọmba 19

Nọmba 19:7-21