Nọmba 18:12 BIBELI MIMỌ (BM)

“Mo fún ọ ní gbogbo èso àkọ́so tí àwọn ọmọ Israẹli ń mú wá fún mi lọdọọdun, ati òróró tí ó dára jùlọ, ọtí waini tí ó dára jùlọ, ati ọkà.

Nọmba 18

Nọmba 18:3-19