Nọmba 16:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo wọn, ati ohun ìní wọn, ati àwọn eniyan wọn, lọ sí ipò òkú láàyè, ilẹ̀ panudé, wọ́n sì ṣègbé kúrò láàrin ìjọ eniyan Israẹli.

Nọmba 16

Nọmba 16:26-41