Nọmba 16:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí àwọn ọkunrin wọnyi bá kú ikú tí kò mú ìbẹ̀rù lọ́wọ́ láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun, a jẹ́ wí pé kì í ṣe OLUWA ni ó rán mi.

Nọmba 16

Nọmba 16:22-34