Nọmba 16:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Olukuluku wọn sì mú àwo turari tirẹ̀, wọ́n fi ẹ̀yinná ati turari sí i, wọ́n sì dúró ní ẹnu ọ̀nà Àgọ́ Àjọ pẹlu Mose ati Aaroni.

Nọmba 16

Nọmba 16:12-25