Nọmba 15:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ìjọ eniyan bá mú un lọ sẹ́yìn ibùdó, wọ́n sì sọ ọ́ lókùúta pa gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose.

Nọmba 15

Nọmba 15:27-41