Nọmba 15:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Òfin kan náà ni ó wà fún gbogbo àwọn tí o bá ṣẹ̀ láìmọ̀, ìbáà ṣe ọmọ Israẹli tabi àjèjì tí ń gbé láàrin ilẹ̀ Israẹli.

Nọmba 15

Nọmba 15:28-34