Nọmba 15:26 BIBELI MIMỌ (BM)

A óo dáríjì gbogbo ìjọ eniyan Israẹli ati àwọn àjèjì tí ń gbé ààrin wọn nítorí pé gbogbo wọn ni ó lọ́wọ́ sí àṣìṣe náà.

Nọmba 15

Nọmba 15:16-28