Nọmba 15:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ mú ọrẹ wá fún OLUWA lára àwọn àkàrà tí ẹ kọ́kọ́ ṣe gẹ́gẹ́ bí ọrẹ láti ibi ìpakà.

Nọmba 15

Nọmba 15:18-27