Nọmba 15:16-19 BIBELI MIMỌ (BM)

16. Òfin ati ìlànà kan náà ni yóo wà fún ẹ̀yin ati àjèjì tí ń gbé pẹlu yín.”

17. OLUWA sọ fún Mose pé, “Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé,

18. Nígbà tí ẹ bá dé ilẹ̀ tí mò ń mu yín lọ,

19. tí ẹ bá jẹ ninu oúnjẹ ilẹ̀ náà, ẹ óo mú ọrẹ wá fún OLUWA.

Nọmba 15