Nọmba 14:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose dá wọn lóhùn pé, “Kí ló dé tí ẹ fi ń ṣe àìgbọràn sí àṣẹ OLUWA nisinsinyii? Ohun tí ẹ fẹ́ ṣe yìí kò ní yọrí sí rere.

Nọmba 14

Nọmba 14:35-45