Nọmba 14:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ óo kú ninu aṣálẹ̀ yìí; gbogbo yín; ohun tí ó ṣẹ̀ láti ẹni ogún ọdún lọ sókè, gbogbo ẹ̀yin tí ẹ kùn sí mi.

Nọmba 14

Nọmba 14:20-30