Nọmba 14:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé àwọn Amaleki ati ará Kenaani ń gbé àfonífojì, ní ọ̀la, ẹ gbéra, kí ẹ gba ọ̀nà Òkun Pupa lọ sinu aṣálẹ̀.”

Nọmba 14

Nọmba 14:21-33