Nọmba 14:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí àwọn eniyan náà ti ń gbèrò láti sọ wọ́n lókùúta pa ni wọ́n rí i tí ògo OLUWA fara hàn ní Àgọ́ Àjọ.

Nọmba 14

Nọmba 14:1-17