Nọmba 13:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Orúkọ àwọn ọkunrin tí Mose rán láti lọ ṣe amí ilẹ̀ náà nìyí. Mose sì yí orúkọ Hoṣea ọmọ Nuni pada sí Joṣua.

Nọmba 13

Nọmba 13:11-23