Nọmba 13:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA sọ fún Mose pé,

2. “Rán amí lọ wo ilẹ̀ Kenaani tí mo fún àwọn ọmọ Israẹli. Ẹnìkọ̀ọ̀kan tí ó bá jẹ́ olórí láti inú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan ni kí o rán.”

Nọmba 13