Nọmba 12:5 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA sì dúró ní ẹnu ọ̀nà Àgọ́ Àjọ ninu ọ̀wọ̀n ìkùukùu, ó sì pe Aaroni ati Miriamu, àwọn mejeeji sì jáde siwaju.

Nọmba 12

Nọmba 12:3-7