Nọmba 12:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n sì fi Miriamu sí ẹ̀yìn ibùdó fún ọjọ́ meje, àwọn eniyan náà kò sì kúrò níbẹ̀ títí di ìgbà tí wọ́n mú un pada.

Nọmba 12

Nọmba 12:13-16