Nọmba 12:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Miriamu ati Aaroni sọ̀rọ̀ òdì sí Mose nítorí pé ó fẹ́ ọmọbinrin ará Kuṣi ní iyawo.

Nọmba 12

Nọmba 12:1-11