Nọmba 11:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Joṣua, ọmọ Nuni, iranṣẹ Mose, ọ̀kan ninu àwọn olùrànlọ́wọ́ rẹ̀ wí fún Mose pé, “Pa wọ́n lẹ́nu mọ́.”

Nọmba 11

Nọmba 11:19-33