Nọmba 11:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose jáde, ó lọ sọ ohun tí OLUWA sọ fún àwọn ọmọ Israẹli; ó sì mú àwọn aadọrin olórí náà wá sí ẹnu ọ̀nà Àgọ́ Àjọ.

Nọmba 11

Nọmba 11:23-31