Nọmba 10:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ẹ bá kọ́ fọn fèrè ìdágìrì, àwọn tí wọ́n pa àgọ́ sí ìhà ìlà oòrùn Àgọ́ yóo ṣí, wọn yóo sì tẹ̀síwájú.

Nọmba 10

Nọmba 10:1-8