Nọmba 10:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbàkúùgbà tí Àpótí Majẹmu OLUWA bá ṣí, Mose á wí pé, “Dìde, OLUWA, kí o sì tú àwọn ọ̀tá rẹ ká, kí o sì mú kí àwọn tí ó kórìíra rẹ sá.”

Nọmba 10

Nọmba 10:32-36