Nọmba 10:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose sì wí pé: “Jọ̀wọ́ má fi wá sílẹ̀, nítorí pé o mọ aṣálẹ̀ yìí dáradára, o sì lè máa darí wa sí ibi tí ó yẹ kí á pa àgọ́ wa sí.

Nọmba 10

Nọmba 10:28-32