Nọmba 10:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn afọnfèrè bá fọn fèrè mejeeji, gbogbo àwọn ọmọ Israẹli yóo wá sọ́dọ̀ rẹ ní ẹnu ọ̀nà Àgọ́ Àjọ.

Nọmba 10

Nọmba 10:1-13