Nọmba 1:37-39 BIBELI MIMỌ (BM)

37. jẹ́ ẹgbaa mẹtadinlogun ó lé egbeje (35,400).

38. Ninu ẹ̀yà Dani, àwọn tí wọ́n tó ẹni ogún ọdún, tí wọ́n tó lọ sójú ogun, gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn ní ìdílé-ìdílé

39. jẹ́ ẹgbaa mọkanlelọgbọn ó lé ẹẹdẹgbẹrin (62,700).

Nọmba 1