Nọmba 1:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu ẹ̀yà Manase, àwọn tí wọ́n tó ẹni ogún ọdún, tí wọ́n tó lọ sójú ogun, gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn ní ìdílé-ìdílé

Nọmba 1

Nọmba 1:24-39